Home Lyrics Mohbad’s Beast & Peace lyrics speaks a lot

Mohbad’s Beast & Peace lyrics speaks a lot

Mohbad beast & peace instrumental

 Mohbad – Beast & peace Lyrics

(The winds will come)

(To steal the words I say) Imole

Ahn

Ahn, mó silent mood, but beast ní mí

Mo lé cause violence but still, peace ní mí

You don’t have to hurt me, before you win

You don’t have to kill somebody before you sin

Óṣá lé browse, láì dè ló sub oh

Òde lé go far without God oh

So, mó dúró t’Olùwà

So, kò kín ṣe irú wá

Even tọbà fún yín làbọ pẹ’lú spoon, ẹ lè j’ojú wá

Èmi má dẹ tí bad, láti àyé la’dì-la’dì

Láti àyé 1990 tó ńlù beat pati-pati

Èmi tímo feel bad, mó dẹ tí feel good

Now, mó feel better, Surulere bí Ojuelegba

Torípé mó wọ ńkán, wọn sọ pé mowà on drug

Now, mowà on top, life mí òdẹ ní contour

Mó pàwọn ni Naija, ó tún báwọn ní London

Fún wọn ní KPK, Ponmo, Light boy wo, mo ńta’na

(Light-boy mo ńta’na)

Uh, mummy mí àti daddy mí, wọn kàn ló ń question mí

Wọn ní, “Ìbò l’otí rí vibe yi, ṣé ọwọ demon?”

Àwọn tọ senior mí, wọn bèrè, “Where you see money?”

Àwọn tí mó jùlọ, wọn photocopy mí

First cashout mí, ọmọ ìyá, mó dè fí rá bazooka

Mo kó fún àwọn sharp shooter

Ẹ má bínú tọbá dá sí’ta

Tra-ta-ta-ta-ta-ta fún àwọn fake nigga

Àwọn t’ofẹ shame mí

Wo, èmi wá shameless

Wọn fẹ stain white mí, but mo wá stainless

Àwọn nigga tọ leave mí, wọn lé rí realness

Torí pé silence mí, no mean say na weakness

Shoutout sí Iba J, Diarra, pẹ’lú Hayan

CY, Darosha, Prime Boy

Spending with my daddy, life mí wá splendid

Ológo, Zomo, TIA, Bella

(Chukwuchilly)

Soul

Mí ṣámọ

Wọn ní irú ẹ

Irú ẹ tóní, kò kíń ṣe original

(Boombah)

O fẹ, o fẹ sùn mó ní

But, kò kíń ṣe òun gan-gan

Source : NAIJALEASH

Get More Music at NAIJALEASH MUSIC